- YORUBA VERSION
- 1
- E JE KA FI'IMO SOKAN
- ëTORI ILE BABA WA
- LATI TUN SE
- LATI GBE GA
- FUN ëLOSIWAU RERE
-
- 2
- IJA IREPO LO YE WA
- KA JA FUN ëLE BABA WA
- NITORI WA
- ëTORI OMO WA
- NITORI OJO OLA
-
- 3
- OMO ODUNDUWA NI WA
- NIBIKIBI TA BA WA
- KA SI MA RANTI
- PE A O PADA SILE
|
- ENGLISH TRANSLATION
- 1
- IN UNITY LET'S STAND
- ON BEHALF OF OUR FATHERLAND
- TO REBUILD IT
- TO REFORM IT
- FOR THE BETTERMENT OF ALL
-
- 2
- LET ALL OF US UNITE
- TO DEFEND OUR MOTHERLAND
- FOR OUR PROGRESS
- AND FOR OUR CHILDREN'S
- AND FOR ALL POSTERITY
-
- 3
- ODUDUWA IS OUR SPRING
- WHEREVER WE MAY BE
- LET'S BE KINFOLKS
- AND REMEMBER
- THAT HOME IS HOME FOR US
|